Kòsí Ìrinàjò Ilẹ̀ Òkèèrè Fún Àwọn Alákòóso Ètò Ìjọba Orílẹ̀-èdè Malawi- Ààrẹ Lazarus Chakwera
Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Malawi, Lazarus Chakwera ti gbé ìgbésẹ̀ akin lójúnà àti dóòlà ọrọ̀ ajé Orílẹ̀-èdè naa eyi ti o ti dẹnu kọlẹ̀
Lara awọn igbesẹ naa ni fífi òfin de ìrìnàjò ilẹ̀ òkèèrè fún awọn osiṣe ijọba
Igbesẹ naa wa lara ọna lati doola ọwọ Orilẹ-ede Malawi eyi ti idiku tide ba gbara rẹ, eyi ti o waye ni ọjọ kẹwaa, osu kọkanla .