Ààrẹ South Sudan Salva Kiir Mayardit tí yọ́ Ọgá Àgbà Ọlọ́pàá Majak Akec Balok tí orílẹ̀-èdè náà lẹyìn àwọn rògbòdìyàn ìdìtẹ̀ gbájọba.
Ààrẹ sọ nínú àsẹ rẹ̀ tó ká sórí ilé iṣẹ́ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ ní (South Sudan Broadcasting Corporation SSBC) ṣùgbọ́n ìjọba kò sọ ìdí kánkan fún ìpinnu náà.