Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Tinubu Gúnlẹ̀ Sí Orílẹ̀-èdè Saudi Arabia

0 60

Ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu ti gúnlẹ̀ sí ìlú Riyadh láti kópa nínú àpérò tí yóò wáyé ní Orílẹ̀-èdè Saudi-Arabia

 

Ààrẹ Tinubu gbéra kúrò ní ìlú Abuja ní àyájọ́ Ọjọ́bọ̀ lo sí ìlú Riyadh, ní Orílẹ̀-èdè Saudi Arabia láti kópa nínú àpérò tí ìrètí wà pé yóò wáyé ní Orílẹ̀-èdè Saudi Arabia ní ọjọ́ kẹwàá osù kọkànlá ọdún 2023

 

Ìrètí wà pé Ààrẹ yóò lo ànfààní náà láti pàrọwà sí àwọn olùdókoòwò ilẹ̀ òkèèrè fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ lójúnà àti mú ìgbòòrò àti ìdàgbàsókè bá ètò ọrọ̀ ajé.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button