Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹgbẹ́ ọ̀dọ́ ní àtúnyàn Uzodinma yóò fìdí ìdàgbàsókè múlẹ̀ ní Imo

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 86

Ìgbìmọ̀  ẹgbẹ́ àwọn ọ̀dọ́ Ohaji lápapọ̀ (NACOY),  ti rọ àwọn olùdìbò ní Imo láti tún dìbò yan Gómìnà Hope Uzodimma fún ìgbà ẹ̀ẹ̀kejì láti fìdí ètò ìdàgbàsókè ìrónilágbára tó ń lọ lọ́wọ́ báyìí múlẹ̀.

Adari awọn obinrin ti ẹgbẹ ibaraẹniṣepọ oloṣelu, Omidan Susan Amadi, pe ipe yii lasiko ipolongo ibo ti ẹgbẹ ijọba ibilẹ Mgbirichi, Ohaji-Egbema ṣe agbekalẹ rẹ ni ɔọjọ Aiku.

Amadi wa gboriyin fun ipa ti  Uzodimma ko ninu eto ironilagbara bii, Imọ iṣẹ Akanṣe Imo, eto ikọṣẹ  ti wọn diidii ṣegbekalẹ rẹ fun awọn ọdọ.

Osọ pe iṣẹ Akanṣe naa nikapa lati ṣẹgun airiṣẹ ṣe, ti yoo si ṣe agbega ilọsiwaju awọn ọdọ, yi awọn ọdọm pada si daradara ti yoo si tun ṣe atunṣe lori eto aabo.

O wa tunbọ rọ awọn ọdọ agbegbe naa, paapaa julọ awọn obinrin, lati pa ero ọkan wọn da lori iṣẹ ibaraẹniṣepọ, oṣelu, ẹkọ ati ọrọ aje si bii ti awọn ẹgbẹ wọn lọkunrin.

O wa gba awọn ọdọ nimọran lati tu yayay tu yaya lasiko idibo gomina ọjọ kọkanla, oṣu kọkanla, lati ṣe ojuṣe wọn.

Leave A Reply

Your email address will not be published.