Take a fresh look at your lifestyle.

Olùṣe Fíìmù Ọmọ Nàìjíríà Se Àseyege Ní New York

0 194

Ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè yi, Idorenyen Uko, ti se aseyori alailẹgbẹ nigba ti o se fiimu, o tún dàírẹ̀tì rẹ̀, ó sì tún gbèè jáde, èyí tó se afihan ọ̀nà gidi tó gbà sọ ìtàn àti àwòrán rẹ, èyí tó yàtọ̀.

Uko sẹ̀ wá láti ìpínlẹ̀ Akwa Ibom, o gbé èsì ìdánwò, “cumulative grade point average of 4.00.” jade ní ibi ẹ̀kọ́ rẹ̀.

Níbi ẹ̀kọ́ náà, Uko se fíìmù, ó dàírẹ̀tì rẹ̀,, ó tún gbe jade, fiimu bíi “Sincerely Me” and “Error Connection.”  lo mú kí o se aseyege to ga jù to fi gba NYFA ní orílẹ̀-èdè New York.

Àwọn ẹbí, ará, àti ọ̀rẹ tí wọn jọ jade ni ilé ìwé náà ló péjọ síbi ayẹyẹ náà láti ba se àjoyọ̀ sí àtẹ̀gùn ibi rere àti ọjọ́ ọ̀la tó dára.

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Leave A Reply

Your email address will not be published.