Ògbòntàrìgì agbábọ́ọ̀lù ẹlẹ́yin lórí tabtili ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Dazzi Gosa, ti gba àmì ẹ̀yẹ Bàbà nígbà ti o lù enìkejì rè, Gutierrez Lopez Yan ní ayò méjì sí òdo (2:0) níbi ìdíje Invictus tó ń lọ lọ́wọ́.
Ikọ̀ “team Nigeria” tún ṣe àṣeyọrí nínú ìdíje mìíràn -irin gbigbe oní ìwọ̀n, ọ̀kàndínláàdọ̀rin kílógīràmù (69kg) láti ọwọ́ Peacaker Azuegbulam.
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san