Take a fresh look at your lifestyle.

Àìsàn Kidinrin: Àwọn Onímọ̀ kìlọ̀ Fún Àwọn Ènìyàn Lórí Oúnjẹ Inú Agolo.

0 91

Àwọn onímọ̀ ìlera nípa oúnjẹ tó ń Sara lọ́rẹ kìlọ̀ fún àwọn ènìyàn lórí oúnjẹ inú Agolo ní jíjẹ, wọn ní nítorí o léwu fún Kidinrin.

Wọn ní àwọn oúnjẹ inú Agolo bi ẹran, èso, àti bẹẹ bẹẹ lọ n ṣe akoba ńlá fún Kidinrin, o sí n  jẹ kí itó Suger pọ sí.

Àwọn onímọ̀ ilera lágbayé ní àìsàn jẹjẹrẹ Kidinrin ti wa gbilẹ  lágbayé báyìí

Umeizudike ṣàlàyé wí pé bí àwọn ènìyàn bá lè sa fún oúnjẹ inú Agolo yóò mú kí àìsàn Kidinrin di kún lágbayé

Leave A Reply

Your email address will not be published.