Take a fresh look at your lifestyle.

Orílẹ̀-èdè Russia Máa Borí “Ibi”, Kim Fi Dá Putin Lójú

0 95

 

Olórí orílẹ̀-èdè North Korea, Kim Jong Un ti sọ fún ààrẹ orílẹ̀-èdè Russia, Vladimir Putin ni ọjọ́ Ojọ́rú pé ó dá òun lójú pé ọmọ ogun Russia àti àwọn ènìyàn rẹ̀ yóò bóri ” Ibi” látàrí ogun Ukraine.

Kí ó tó bẹ̀rẹ̀ sí ní ma sọ̀rọ̀ nípa ìlera Putin,isegun “Great Russia”,, àjọṣepọ̀ Korea pẹ̀lú Russia àti ìlera áwọn tó péjú pésẹ̀ síbẹ̀, Kim ṣọ pé ó dá òun lójú pé orílẹ̀-èdè Russia yóò bóri dandan, tí Moscow pe èyí ní ” Àkànṣe ìkọ̀lù ọmọ ogun” ní Ukraine.

Àwọn alátakó ní ilẹ̀ aláwọ̀ funfun sọ pé àwọn funra ṣí Russia pé wọ́n fẹ́ lọ kó nǹkan ìjà ogun wá láti lò fún ògún òun pẹ̀lú Ukraine ni, Moscow àti Pyongyang
sẹ́ pé èyí kò rí bẹ́ẹ̀.

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Leave A Reply

Your email address will not be published.