Akọrin ọmọ Nàìjíríà kan, Oníwàásù
Ben Kenechukwu Onyemechalu, tí wọ́n mọ̀ sí FadaBen, ti mú inú àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ dùn nípa gbígbé díẹ̀ ṣókí àwo Fídíò tó fé jáde síta fún ìtọ́wò tó pè ní ” Idán rẹ̀ ńbẹ ní ọwọ́ rẹ”.
Akọrin náà gbé èyí jáde lórí òpó ẹ̀rọ ayélujára rẹ ní ọjọ Ìṣẹgun pé ògidì orin náà yóò jáde ní ọjọ Àìkú, ọjọ kẹtàdínlógún, oṣù kẹsàn án, ọdún yìí ní aago méje àsálẹ́.
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san