Take a fresh look at your lifestyle.

Iran Jẹ́rìí Sí àtimọ́lé Ọmọ Sweden, Òṣìṣẹ́ Àjọ Yúrópù

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 165

Adájọ Iran kàn tí jẹ́rìí sí pé ọmọ Orílẹ̀-èdè Swedish kàn tí n ṣíṣẹ́ fún Àjọ Yúrópù [EU] tí wà ní àtimọ́lé, ìgbésẹ túntún ló wáyé látàrí gbọnmisi-omi-o-to tó ń ṣẹ̀lẹ̀ láàrín Orílẹ̀-èdè Iran àti Àjọ Yúrópù.

Sweden àtí Àjọ Yúrópù sọ pé ni ọsẹ tó kọjá pé ọmọ orílẹ̀-èdè Sweden kàn tí wà ní àtimọ́lé ní Iran. Sweden sọ pé Johan Floderus tí wà ní àtimọ́lé ní Oṣù Kẹ́rin, ọdún 2022 fún ẹsùn tí àwọn ẹbí rẹ̀ sọ́ pé o jẹ́ ayọjuran.

“A tí fí ọmọ orílẹ̀-èdè Sweden sí ẹ̀wọ̀n lábẹ́ òfin àtí pé láìpẹ́ wọ́n yóò fí ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ọ̀ran rẹ̀ hàn lẹ́yin ìwádìí ilé ẹjọ́. ágbẹ́nùsọ tí ètò ìdájọ tí Iran, Masoud Setayeshi, sọ.

Ágbẹ́nùsọ náà kó ṣé àlàyé jù bẹ́ẹ̀ lọ́.

Leave A Reply

Your email address will not be published.