Take a fresh look at your lifestyle.

Ètò Ìbímọ Di Ọ̀fẹ́ Fún Àwọn Aláboyún Báyìí:Gómìnà ìpínlẹ̀ Anambra

0 160

Gómìnà ìpínlẹ̀ Anambra Chukwuma Soludo ti ṣètò Ìbímọ ọ̀fẹ́ fún àwọn Aláboyún ni ìpínlẹ̀ náà ni àsìkò tó kù kí  ìjọba rẹ parí 

Gómìnà ṣe àpèjúwe ìrànlọ́wọ́ yìí gẹ́gẹ́ bíi òun tí òun lè fi ṣe ìrànlọ́wọ́ css lákòkòó ọwọn gógó epo rọ̀bì yìí

Ó ni àwọn ẹtọ míràn tí wa nílé fún àwọn òṣìṣẹ́, àwọn tó tí fí èyítí,  àti àwọn ará ìlú látàrí ọwọ̀n gógó epo rọ̀bì yìí.

Bákannáà kọmísọ́nà fún ètò ìlera ni ìpínlẹ̀ Anambra Afam Obifike, so wí pé ètò náà yóò wa kàkàkí ni àwọn ilé ìwòsan ìjọba ìbílẹ̀ tó kù ní ìpínlẹ̀ náà.

O wà rọ àwọn Aláboyún láti lo àsìkò àti ànfààní náà daradara.

Leave A Reply

Your email address will not be published.