Ààrẹ orílẹ̀-èdè South Africa, Cyril Ramaphosa yóò ṣáájú àwọn ikọ̀ adarí ijọba lọ sí ìlú Hammasnkraal to wà ni àríwá Olu ilu South Africa, Pretoria, níbi tí àrùn Kolera to lagbara ti gbòde.
Ààrẹ CyrilR amaphosa sọ pé àrùn náà ti jẹ́ kí àdánù ńlá kí ó wà, ìjọba sí ti ń ṣe akitiyan láti má jẹ́ kí ó gbèrú sí.
Ènìyàn merindinlogbon ló ti gbẹ̀mí mì látàrí àrùn náà.
Ìròyìn ró pé Àádòje ènìyàn ni wọ́n sì ti gba ìtọ́jú.
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san