Take a fresh look at your lifestyle.

Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ṣe Ìfilọ́lẹ̀ Fífún Àwọn Ọmọ Ilé Ìwé Ni Oúnjẹ Ní Ìpínlẹ̀ Bayelsa.

0 109

Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ṣe Ìfilọ́lẹ̀ Fífún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní ounjẹ ni ìpínlẹ̀ Bayelsa, ki o lẹ jẹ ànfààní láti fí àwọn ọmọ sí ilé ẹ̀kọ́.

Ètò yìí ni mínísítà fún ọ̀rọ̀ àwọn ará ìlú àti ọ̀rọ̀ tó ńlọ lórí afẹfẹ , Sadiya Umar Farouq fí lọlẹ ni Yenagoa, ni ìpínlẹ̀ Bayelsa.

Ọ̀gá àgbà fún isé tí o ba òfin mú, agbẹjọro Garba Haganawega lo sójú mínísítà náà, ó ní ètò yìí yóò jẹ ànfààní fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní àgbáyé.

Gómìnà ìpínlẹ̀ Bayelsa Sẹ́nátọ̀ Douye Diri ti komísọ́nà fún ètò èkó sójú fún , ọ̀mọ̀wé E.Emelah , sọ wí pé ìjọba ohun ṣe àtìlẹ́yìn fún ìjọba Ààrẹ Buhari láti rí wí pé ohun gbogbo ṣiṣẹ́ pọ bakanna.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button