Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn Ọmọ Ológun orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Tako Ẹ̀sùn Tí Wọ́n Fi Kàn Wọ́n Nípa Ìwà Ibàjẹ́. 

0 159

Àwọn ẹgbẹ́ ọmọ ológun Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni àwọn ṣe àkíyèsí àwọn ìròyìn tí ilé ìròyìn Sahara gbé síta lórí wí pé àwọn ẹgbẹ́ ọmọ ológun n ba ìlú jẹ ,ni èyí tí kò rí bẹ́ẹ̀.

Gẹgẹ bí ìròyìn tí sọ ẹgbẹ̀ NA se àkíyèsí wí pé àwọn ìròyìn náà ní owó nínú, nítorí o tako àwọn ohun tí ẹgbẹ́ jẹ.

Wọ́n ní àwọn sisé takuntakun láti rí wí pé Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà wa ni àlàáfíà àti irẹpọ.

Wọn ní ìròyìn afẹ́fẹ́ náà je eyin ti kò péye tọ eléyìn tí kò sí ní ìtẹ̀wọọ́gbà

Gbogbo ọmọ ológun ni won ti rọ láti wà ní àlàáfíà áti ìrẹ́pọ̀ kí ìròyìn ki kò péye  ma bá tún won ká

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button