Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹ Kópa Nínú Ètò Ọ̀gbìn Lójúnà Àti Tán Ìsòro Ọ̀wọ́ngógó Oúnjẹ- Akọ́ṣẹ́mọṣẹ́

0 159

Àrọwà ti wá fún àwọn tí ó wà ní ìlú ńlá láti kópa nínú ètò ọ̀gbìn kí oúnjẹ le è pọ̀ lọ́pọ̀ yanturu, yóò sì tún mú kí ìsòro ọ̀wọ́ngógó oúnjẹ di àfìsẹ́yìn tí egúngún ń fi aṣọ.

 

Àrọwà náà wáyé nínú àpérò ti ọdún 2023, tí ó wáyé ní ọjọ́ Àbámẹ́ta, ní ìlú Èkó, tí àkọmọ̀nà rẹ̀ jẹ́ “Ọ̀nà Àbáyọ Sí Ìpèsè Oúnjẹ Ní Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà.

 

Ọ̀mọ̀wé Adelaja Adesina rí kíkópa nínú ètò ọ̀gb̀in ní ìlú ńlá gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà àbáyọ sí ìsòro ọ̀wọ́ngógó oúnjẹ , Ó wá pàrọwà sí àwọn ará ìlú ńlá láti gbin ohun ọ̀gbìn sí àyíká ilé wọn.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button