Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹ Fọwọ́sowọ́pọ̀ Láti Jẹ Ànfààní Ìjọba: Akọ́ṣẹ́mọsẹ́ kan Pàrọwà Sí Àwọn Alápatà

0 145

Alámòjútóó àgbà fún àwọn ọ̀rọ̀ ohun ọ̀sìn ní Ìpínlẹ̀ Plateau, Dokita Sipak Shse’et ti pàrọwà sí àwọn alápatà ní ìpínlẹ̀ náà láti gbé ìgbé àlàáfíà ní ibùdó ìpa ẹran, lójúnà àti jẹ ànfààní ìjọba.

 

Shase’et sàlàyé síwájú pe ìjọba àpapọ̀ ti sètò ẹ̀rọ amú nǹkan tutù, ṣùgbọ́n látàrí àìsí ìsàkóso tí ó gún régé, kò sí ànfààní láti gbà á lọ́wọ́ ìjọba.

 

 

Ó wá pèpè fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ láàrin àwọn ọmọ ẹgbẹ́ náà, kí ó le è fún wọn ní ànfààní láti gbádùn ètò ìjọba. Ó sì jẹ́jẹ̀ẹ́ àtìlẹyìn ìjọba láti pàsẹ ohun èlò tí ó péye fún ìgbòòrò iṣẹ́ wọn.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button