Take a fresh look at your lifestyle.

Arólé Oòduà Ọba Adeyeye Ojaja II Ṣé Ìfilọ́lẹ̀ Ẹ̀sìn Adúláwọ̀ Ní Orílẹ̀-èdè Brazil

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

2 1,346

Ẹní ọ̀wọ̀ àtí alága àwọn Ọba lorílẹ̀-èdè Nàìjíríà (National Traditional Council), Ọọ̀ni tí ilé Ifẹ, H.I.M Adeyeye Enitan Ogunwusi, Ọjaja II, tí ṣé ìfilọ́lẹ̀ ọjọ́ ẹsìn ìbílẹ̀ adúláwọ̀ tí ọdọọdún tí á pé àkọlé rẹ̀ ní “Ọjọ́ Ìṣẹ̀ṣé,” ní orílẹ̀-èdè Brazil.

O ṣé ìfilọ́lẹ̀ náà ní gbọ̀ngán ayẹyẹ Ààrẹ ni Brasilia, nígbàtí Ààrẹ Lula da Silva gbàlèjò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọjọ́ ìbẹ̀wọ̀ iṣẹ́ rẹ̀ sí Sao Paulo, Rio De Janeiro, Salvador, Bahia àtí Brasilia.

Kábíyèsí Ọba Adeyeye Enitan Ogunwusi, wà ní Orílẹ̀-èdè Brazil ní ìtèsíwájú ìrìn-àjò àgbáyé rẹ̀ fún ètò Àlàáfíà àti Ìlọsíwájú Àwọn ènìyàn Áfíríkà (African People’s Peace and Progress Agenda) àtí isọdọkan àwọn adúláwọ̀ tó jù ọgọrùn mílíọ̀nù lọ́ ní Orílẹ̀-èdè Brazil, tí a pé ní “Ilé labọ ìsinmi.”

O ló àbẹwò náà láti mọ rírí àwọn iṣẹ́ ribiribi tí àwọn adúláwọ̀ àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè náà tí ṣé, Ó sí rọ́ Ààrẹ Lula látí mú àwọn ìlérí rẹ̀ ṣẹ̀ lórí fífi ààyè gbá àwọn adúláwọ̀ ọmọ orílẹ̀-èdè náà nínú ìjọba rẹ̀.

Nínú èsì tí rẹ̀, Ààrẹ Lula da Silva dúpẹ lọwọ́ Ọọni, o sí gbóríyìn fún Ọba náà fún ìpínu rẹ̀ sí ìṣọ̀kan àwọn adúláwọ̀ ọmọ orílẹ̀-èdè òún (Afro-Brazil) àtí pàápà àwọn ọmọ ilẹ̀ Áfíríkà làgbáyé èyí tí yóò bí àlàáfíà káríayé.

Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Brazil ṣé ìdánilójú pé Ọjọ́ Ẹsìn Áfíríkà ọlọdọọdun tí dì ṣíṣé – Ọjọ́ Ìṣẹ̀ṣé tí dì dandan ní orílẹ̀-èdè Brazil.

Aróle Oodua rìn ìrìn-àjò náà pẹ̀lú ogójì ènìyàn rẹ̀, èyí tí àwọn Olori méjì wà nínú rẹ̀, àwọn Ọba, àwọn òníṣẹ́ṣé àtí àwọn mìíràn.

2 Comments
 1. Megan Atkinson says

  Hi there,

  We run an Instagram growth service, which increases your number of followers both safely and practically.

  – We guarantee to gain you 400-1000+ followers per month.
  – People follow you because they are interested in you, increasing likes, comments and interaction.
  – All actions are made manually by our team. We do not use any ‘bots’.

  The price is just $60 (USD) per month, and we can start immediately.

  If you’d like to see some of our previous work, let me know, and we can discuss it further.

  Kind Regards,
  Megan

 2. Steve Watson says

  Hi,

  We’d like to introduce to you our explainer video service, which we feel can benefit your site yoruba.von.gov.ng.

  Check out some of our existing videos here:
  https://www.youtube.com/watch?v=bWz-ELfJVEI
  https://www.youtube.com/watch?v=Y46aNG-Y3rM
  https://www.youtube.com/watch?v=hJCFX1AjHKk

  All of our videos are in a similar animated format as the above examples, and we have voice over artists with US/UK/Australian accents. We can also produce voice overs in languages other than English.

  They can show a solution to a problem or simply promote one of your products or services. They are concise, can be uploaded to video sites such as YouTube, and can be embedded into your website or featured on landing pages.

  Our prices are as follows depending on video length:
  30 seconds = $195
  1 minute = $259
  1-2 minutes = $379
  2-3 minutes = $489

  *All prices above are in USD and include a full script, voice-over and video.

  If this is something you would like to discuss further, don’t hesitate to reply.

  Kind Regards,
  Steve

Leave A Reply

Your email address will not be published.