Take a fresh look at your lifestyle.

 Ọ̀dọ́mọdé afi eré bọ́ọ̀lù dárà ti jẹ ẹ̀bùn ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ fún ọdún márùn-ún

0 139

Gomina ipinlẹ Anambra, Ọmọwe Chukwuma Soludo ti ṣe ileri wipe ijọba ilu ti setan lati ṣe iranlọwọ fun ọmọ ọdun mẹrinla afi erẹ bọọlu dara, Chinonso Eche ti o ṣe di eniti orukọ rẹ farahan ninu iwe agbaye Guinness (Guinness World Record) nigba karùn-ún.

Gomina Soludo ti o ṣe ikede ẹkọ ọfẹ ọdun márùn-ún fun Eche ati ikeji rẹ Victor Richard, sọ pe wọn ma mu eto eko wọn lọkunkundun, ati wipe wọn yọọ jẹ ki wọn ni akoko ati mojuto ẹbun wọn.

 

Níbití Gomina ati iyawo rẹ, Nonye ti n wo ere bọọlu Eche ati ikeji rẹ ni Soludo ti  sọ wipe eto ijoba ohun je eyiti yóò ṣe aanu awọn eniyan lati ri wipe wọn yẹgẹ ninu ẹbun wọn.

Iyawo Gomina, Nonye sọ wipe ẹbun Eche yatọ, osi ṣe ileri wipe iru ẹbun bayii wà ní iranti ni gbogbo igba.

Leave A Reply

Your email address will not be published.