Take a fresh look at your lifestyle.

Àwẹ̀ Ramadan: Gómìnà Ìpínlẹ̀ Niger Rọ Àwọn Mùsùlùmí Láti Gbàdúrà Fún Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

0 170

Gómìnà ìpínlẹ̀ Niger, Abubakar Sani Bello ti pe àwọn Mùsùlùmí láti lò àkókò oṣù awé láti fi bẹ Ọlọrun fún ọpọ ìbùkún ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

Gómìnà sọ èyí nínú àtẹjáde kan ti agbẹnusọ rẹ̀ Mary Noel Berje ka wí pé ádùrá irẹpọ àti àlàáfíà ni ko pọju lakoko oṣù awé yìí.

 

Ó rọ àwọn mùsùlùmí lati tẹ̀lé ofin àti ìlànà Ọlọrun nínú oṣù awé yìí fún ọpọ àlàáfíà àti ìmísí ọlọrun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button