Take a fresh look at your lifestyle.

A Ó Mójútó Ìpèníjà Tó Ń Dojúkọ Omi Lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà – Mínísítà Adamu

0 187

Ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà sọ pe ibẹrẹ àjọ omi fún ìdá ogójì yoo bẹ̀rẹ̀ ki ọdún mẹwa to pari.

 

Mínísítà fún àjọ omi ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Suleiman Adamu sọ èyí di mímọ̀ níbi ayẹyẹ àgbáyé fún omi, o ni eléyìí yóò ràn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lọ́wọ́ láti mú ìdàgbàsókè bá omi fún lílò gbogbo ènìyàn ní ọdún 2030.

 

Aṣojú fún àjọ nípa oúnjẹ àti ọgbin, Fred Kafeero sọ wí pé àkóbá tí omí nṣe fún oúnjẹ ko kéré, fún ìdí èyí ìyípadà gbọdọ dé ba ètò omi fún àlàáfíà ará ìlú.

 

Àkọlé ayẹyẹ ọdún yii ni : Ọna to yàrá láti mú iyànjú ba ọ̀rọ̀ omi.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button