Take a fresh look at your lifestyle.

Ìdìbò Ọdún 2023: Àwọn Gómìná Tí wọ́n ṣẹ̀ yàn àti àwọn tó wọlé sáà kejì káaàkiri àwọn Ìpínlẹ̀

0 176

Àjọ eleto idibo ti kede awọn gomina tuntun ti o jawe olubori kaakiri ipinlẹ lẹyin igba ti a ti pari idibo gomina ati ile igbimọ asofin to waye ni ọjọ kejidinlogun, osu kẹta, Ọdún 2023

Ẹgbẹ́ Oṣelu APC lo gbegba orókè julọ ni gbogbo ipinlẹ, wọn jawe olubori ni ipinlẹ Jigawa, Katsina, Benue, Sokoto, Eko, Gombe, Ogun, Yobe àti Kwara gẹgẹ bi esi ti ajọ eleto idibo gbe sita

Tí Ẹgbẹ oṣelu PDP si ṣe ipo keji, wọn jawe olubori ni ipinlẹ tuntun bíi Akwa Ibom àti Umo Eno.

Àwọn gomina tuntun ti a fi ibo yàn ti sọ pe, awọn yoo gbaruku ti ara wọn lati ri pe Ijọba wọn fọwọsowọpọ lati Ipinlẹ Eko, Katsina, Ogun, Ọyọ, Akwa Ibom, Gombe àti Yobe ki awọn ipinlẹ wọn ba le ni idagbasoke

 

George Ọláyinká Akíntọ́lá.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button