Gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó tí ó tún jẹ́ olùdíje sí ipò Gómìnà lábẹ́ ẹgbẹ́ òsèlú APC, Ọgbẹni Babajide Sanwo-Olu ti yege ní ìjọba ìbílẹ̀ méjìlélógún nínú ìjọba ìbílẹ̀ ogún tí ó wà ní ìpínlẹ̀ Èkó.
Àjọ INEC kéde èsì ìbò náà ní ọjọ́ Àìkú, ní gbọ̀ngàn ìsàkójọpọ̀ ìdìbò, ní Yaba.
Sanwo-Olu, ẹni tí ó ń díje fún sáà ẹlẹ́ẹ̀kejì ni ó faga-gbága pẹ̀lú Ọlajide Ọladiran ti ẹgbẹ́ òsèlú PDP àti Gbadebọ Rhodes-Vivour ti ẹgbẹ́ òsèlú LP.
Leave a Reply