Ajọ eleto Idibo INEC ti kede Oludije fún ipo gomina labẹ asia ẹgbẹ All Progressives Congress, Gómìnà Muhammadu Yahaya gẹgẹ bi oludije to jawe olubori ni ipinlẹ Gombe
Alakoso Ibo ni Ipinlẹ naa Ọjọgbọn Maimuna Waziri, sọ pe Gomina Yahaya lo jawe olubori pẹlu ibo 342,821
Wọnyi ni esi ibo naa ni gbogbo ijọba ibilẹ Gombe
1. Shongom LGA:
APC: 13, 609
PDP: 13, 412
2. Billiri LGA:
APC: 14, 752
PDP: 23, 066
3. Nafada LGA:
APC: 15, 025
PDP: 9, 378
4. Balanga LGA:
APC: 25, 341
PDP: 20, 085
5. Dukku LGA:
APC: 35, 207
PDP: 14, 181
6. Kaltungo
APC: 21, 015
PDP: 21, 321
7. Gombe LGA
APC: 58, 645
PDP: 31, 605
8. LGA, Kwami
APC: 33, 956
PDP: 17, 454
9. Yamaltudeba
APC: 43, 981
PDP: 28, 538
10. Funakaye
APC: 30, 371
PDP: 17, 332
11. Akko LGA
APC: 50, 919
PDP: 36, 759
George Ọláyinká Akíntọ́lá.