Take a fresh look at your lifestyle.

Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Ẹlẹ́ẹ̀kẹẹ̀wá kò ní fi Ọwọ́ Yẹpẹrẹ Mú Ìpèsè Ohun Amáyédẹrùn- Lọla Ashiru

0 77

Sẹ́nétọ̀ Lọla Ashiru tí ó n sojú ibùdo ẹkun iwo òòrùn Ìpínlẹ̀ Kwara ní ilé ìgbìmọ̀ asòfin àpapọ̀ sàlàyé pé, ilé ìgbìmọ̀ asòfin àpapọ̀ ẹlẹ́ẹ̀kẹẹ̀wá tí yóò gbéra sọ láìpẹ́ yóò mú ìpèsè ohun amáyédẹrùn ní òkúkúdùn láti sọ ayé di gbẹdẹmukẹ fún mùtú-mùwà.

Ashiru fi ọ̀rọ̀ náà léde nígbà tí ó ń sọ̀rọ̀ pẹ̀lú àwọn akọ̀royìn lẹ́yìn ìgbà tí ó kópa nínú ìdìbò Gómìnà ní ìjọba ìbílẹ̀ Ọffa, èyí tí ó wáyé ní ọjọ́ Àbámẹ́ta.

Lára àwọn àfojúsùn rẹ̀ ní síṣẹ ètò ìlera tí ó péye, ìdàgbàsókè ẹ̀kọ́, ìpèsè omi ẹ̀rọ, ìgúnpá fún àwọn onísòwò àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

Leave A Reply

Your email address will not be published.