Olùdíje fún ipo gomina labẹ asia ẹgbẹ All Progressives Congress (APC) Dọkita Dikko Radda ti jawe olubori ninu idibo gomina ti ipinlẹ Katsina to waye ni ọjọ kejidinlogun oṣu kẹta, Ọdun 2023
Alakoso Ibo ni Ipinlẹ naa Ọjọgbọn Mu’azu Abubakar lati ile ẹkọ fafiti Gusau kede Dọkita Dikko Radda gẹgẹ bi oludije to jae olubori lẹyin kika ibo ijọba ibilẹ mẹrinlelogoji pẹlu ibo 859,892 lati rọmi si oludije ẹgbẹ oṣelu PDP, Yakubu Lado níìdí pẹlu ibo 486,620
Awọn mẹtala lo dije du ipo gomina ipinlẹ Katsina
George Ọláyinká Akíntọ́lá.