Ajọ eleto Idibo ti kede Oludije fun ipo gomina labẹ asia ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress (APC) ní Ipinlẹ Ogun, Dapo Abiodun gẹgẹ bi oludije to jawe olubori ninu ibo ọjọ satide
Alakoso Ibo ni Ipinlẹ naa, Ọjọgbọn Kayode Adebowale lo ṣe ikede naa ni bi gbọngan ibo kika ti ajọ eleto idibo ni ipinlẹ ogun, Ti Niyi Ijalaye si ran lọwọ, o sọ pe lẹyin ti wọn ṣe akojọ ati kika ibo ni gbogbo Ijọba Ibilẹ ogún to wa ni ipinlẹ naa, ni o ti fi han pé Abiodun lo jawe olubori
Abiodun gbo omi ewuro si Adebutu loju pẹlu ibo 13,915
Abiodun ni ibo 276,298 ninu gbogbo ibo 663,968 lapapọ
Wọnyi ni esi ibo naa ni gbogbo ijọba ibilẹ Ògùn
1. ODEDA LGA
APC: 11,089
PDP: 8,050
NNPP: 31
ADC: 3,651
2. EGBADO NORTH LGA
APC: 15,331
PDP: 11,627
NNPP: 64
ADC: 12,190
3. EGBADO SOUTH LG
APC: 15,047
PDP: 10,913
NNPP: 75
ADC: 6,435
4. EWEKORO LG
APC: 8,192
PDP: 7,449
NNPP: 60
ADC: 3,881
5. ABEOKUTA SOUTH LG
APC: 19,689
PDP: 24,175
NNPP: 99
ADC: 9,264
6. IJEBU NORTH LG
APC: 18,815
PDP: 15,904
NNPP: 22
ADC: 2,393
7. IKENNE LG
APC: 9,125
PDP: 12,472
NNPP: 09
ADC: 336
8. IJEBU NORTH-EAST LG
APC: 5,408
PDP: 7,086
NNPP: 27
ADC: 1,448
9. IJEBU-ODE LG
APC: 12,907
PDP: 10,714
NNPP: 36
ADC: 1,348
10. ABEOKUTA NORTH
APC: 14,294
PDP: 12,622
NNPP: 34
ADC: 9,143
11. IJEBU EAST LG
APC: 7,883
PDP: 11,242
NNPP: 45
ADC: 1,885
12. REMO NORTH LG
APC: 4,306
PDP: 8,177
NNPP: 06
ADC: 327
13. IPOKIA LG
APC: 21,338
PDP: 19,189
NNPP: 46
ADC: 1,897
14. ODOGBOLU LG
APC: 9,143
PDP: 12,963
NNPP: 10
ADC: 1,281
15. OGUN WATERSIDE LG
APC: 5,878
PDP: 7,716
NNPP: 56
ADC: 2,575
16. IMEKO AFON LG
APC: 9,591
PDP: 6,981
NNPP: 93
ADC: 6,124
17. ADO-ODO OTA LG
APC: 39,006
PDP: 31,022
NNPP: 194
ADC: 12,174
18. OBAFEMI OWODE LG
APC: 15,466
PDP: 11,004
NNPP: 275
ADC: 5,105
19. IFO LG
APC: 20,653
PDP: 16,052
NNPP: 154
ADC: 11,040
20. SAGAMU LG
APC: 13,128
PDP: 17,025
NNPP: 58
ADC: 2,257
George Ọláyinká Akíntọ́lá