Take a fresh look at your lifestyle.

Àkójọpọ̀ Èsì ìbò Gómìnà Gẹ́gẹ́ Bí Ò Ṣe Wáyé Ní Àwọn Ìjọba Ìbílẹ̀ Mẹ́tàlélọ́gbọ̀n Ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́

0 94

Akojọpọ èsì ìdìbò Gómìnà gẹgẹ bí o ṣe wáyé ni àwọn ìjọba Ìbílẹ̀ Metalelọgbọn (33) ni Ẹtì ọjọ Kejidinlogun oṣù yìí (18/03/2023) ní Ìpínlè Ọ̀yọ́ tí bẹrẹ, tí o sì n tẹ síwájú ni Gbongan Mutiu Agboke tó kalẹ sí Ọgbà Àjọ Eleto Ìdìbò INEC to wa ni ìlú ìbàdàn ni Ìpínlè Ọ̀yọ́.

Wọ̀nyí ni èsì ìbò Gómìnà fún àwọn ẹgbẹ òṣèlú Accord, APC, PDP àti LP gẹgẹ bíi àwọn oṣiṣẹ Àjọ Eleto Ìdìbò INEC tó ṣe Akoso àti Akojọpọ èsì fún àwọn ìjọba Ìbílẹ̀ ni Ìpínlè Ọ̀yọ́ ṣe kéde rẹ:

1) Ìjọba Ìbílẹ̀ Ona-Ara
Accord: 1,212
APC: 5,510
PDP: 17,326
LP: 36

2) Ìjọba Ibilẹ Ariwa Iwọ Oòrùn Ìbàdàn
Accord: 1,291
APC: 5,947
PDP: 19,007
LP: 74

3) Ìjọba Ibilẹ Ìlà Oòrùn Ìbàràpá
Accord: 1,885
APC: 7094
PDP: 11,125
LP: 10

4) Ìjọba Ibilẹ Afijio
Accord: 1,357
APC: 5,588
PDP: 13,139
LP: 10

5) Ìjọba Ibilẹ Atiba
Accord: 1,113
APC: 7,484
PDP: 18,389
LP: 15

6) Ìjọba Ibilẹ Orire
Accord: 1,895
APC: 9,216
PDP: 13,767
LP: 17

7) Ìjọba Ibilẹ Gúsù Iwọ Oòrùn Ìbàdàn
Accord: 2,270
APC: 9,491
PDP: 31,273
LP: 166

8) Ìjọba Ibilẹ Oluyole
Accord: 1,386
APC: 6,592
PDP: 21,700
LP: 63

9) Ìjọba Ibilẹ Atisbo
Accord: 1,188
APC: 6,955
PDP: 9,199
LP: 16

10) Ìjọba Ibilẹ Ìlà Oòrùn Ṣakí
Accord: 188
APC: 5,519
PDP: 8,374
LP: 07

11) Ìjọba Ibilẹ Surulere
Accord: 271
APC: 8,882
PDP: 15,554
LP: 173

12) Ìjọba Ibilẹ Ìtèsíwájú
Accord: 2036
APC: 4,597
PDP: 8034
LP: 09

13) Ìjọba Ibilẹ Ogo Oluwa
Accord: 50
APC: 5,570
PDP: 10,930
LP: 17

14) Ìjọba Ibilẹ Irẹpọ
Accord: 388
APC: 9,785
PDP: 7,193
LP: 03

15) Ìjọba Ibilẹ Ọlọrunṣogo
Accord: 998
APC: 4,851
PDP: 5,838
LP: 04

16) Ìjọba Ibilẹ Àríwá Ìlà Oòrùn Ìbàdàn
Accord: 1,564
APC: 8,486
PDP: 29,396
LP: 61

17) Ìjọba Ibilẹ Ogbomosho
Accord: 10
APC: 8,257
PDP: 17,693
LP: 83

18) Ìjọba Ibilẹ Gúsù Iwọ Oòrùn Ìbàdàn
Accord: 1,846
APC: 9,147
PDP: 23,585
LP: 61

Gómìnà Seyi Makinde to tún dije fún ipò Gómìnà labẹ àsìá ẹgbẹ́ òṣèlú PDP, Aṣòfin Teslim Folarin to dije labẹ àsìá ẹgbẹ́ òṣèlú APC, Olóyè Adebayo Adelabu ti ẹgbẹ òṣèlú Accord àti Ọgbẹni Taofeek Akinwale ní àwọn mẹrin nínú àwọn oludije Mérìndínlógún tó du ipò Gómìnà ní ìpínlè Ọ̀yọ́.

Akojọpọ èsì ìbò fún àwọn Ìjọba Ibilẹ Marundinlogun (15) tó kù si n tẹ síwájú.

Abiola Olowe
Ìbàdàn

Leave A Reply

Your email address will not be published.