Take a fresh look at your lifestyle.
Election

Russia Dá Atukọ̀ Òfurufú Tí Ó Ri Ọkọ Òfurufú-Ajagun US Lọ́lá

0 72

Russia ti fi Idalọ̀la Ìpínlẹ Jin àwọn Atukọ̀ Òfurufú meji ti wọ́n tẹ Ofurufu Ajagun US ri sinu Òkun-Dúdú, nígbà tí US jẹ ki o di mímọ́ fún Mínísítà Ààbò Russia wi pé Ọkọ Òfurufú Àmín wọ́n ti gùnlẹ si Orílẹ-èdè Russia.

 

Mínísítà Ààbò orílẹ̀-èdè Russia, Sergei Shoigu nígbà tí wọ́n ń dá àwọn Atukọ̀ Su-27 méjèèjì lọ̀la ni Ọjọ́bọ fi ìdùnnú rẹ han nípa àṣeyọrí láti má jẹ kí Ọkọ Òfurufú yìí ni ànfààní láti sùnmọ̀ bebe Crimea ti wọn ti fi Ote le Moscow.

 

Pro-Kremlin Alatotonu lori Òṣèlú Sergei Markov sọ pé ìdálọ̀la fihàn pe “amin wípé Russia yòó tún bọ máà tẹ Ọkọ Òfurufú US ri.”

 

Olubunmi Adeyẹmọ.

Leave A Reply

Your email address will not be published.