Olùdíje fún ipò Gómìná ẹgbẹ́ òṣèlú PDP ní Ìpínlẹ̀ Jigawa, Mustapha ti dìbò ÌRÒYÌN ORÍLẸ̀-ÈDÈ NÀÍJIRÍÀÌRÒYÌN ÒSÈLÚKÓKÓ INÚ ÌRÒYÌN By Ademola Adepoju On Mar 18, 2023 0 47 Share Olùdíje fún ipò Gómìná ti ẹgbẹ́ òṣèlú PDP, Mustapha Lamido ti dìbò ní Ile-iwe alakọbẹrẹ Bamaina keji ní ibudo idibo Ijọba ibilẹ Birnin Kudu, Ipinlẹ Jigawa #ìdìbò_Gómìnà_Ọdùn_2023 0 47 Share FacebookTwitterWhatsAppEmailLinkedinTelegram