Ile-ẹjọ tó ń rí sí ìwà ọ̀daràn lágbàáyé, International Court of Justice,ICC yóò fi ọwọ́ ofin mu ààrẹ Vladimir Putin ti orílẹ̀-èdè Russia fún awọn ẹ̀sùn ọ̀daràn
Èyí wàyé ní Ọjọ́ Jímọ̀, Oṣù Kẹta Ọjọ kẹtadinlogun, Ọdun 2023 ní. dédé aago mejila kọja isẹju mọ́kànlá ọ̀sán
Ó ṣe é ṣe kí Ọgbẹni Putin fojú ba ilé ẹjọ́ fún ìwà ọ̀daràn lásìkò tó sì ì wà lórí àlééfà..
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìròyìn náà ń bọ̀ láìpẹ́…