Take a fresh look at your lifestyle.

Ìdìbò Gómìná: Osinbajo ti dìbò, Ó Ṣe àfihàn Ìdùnnú rẹ̀ bí ètò ìdìbò yíì ṣe ń lọ 

0 103

Igbákejì Ààrẹ Nàíjíríà, Ọ̀jògbọ́n Yemi Osinbajo àti ìyàwó rẹ, Dolapo, ti dibo wọn ni bi idibo Gomina ati ile igbimọ aṣofin Ipinle ni ọjọ Satidee ni orílẹ̀-èdè Nàíjíríà.

 

Wọn dibo ni nnkan bi aago mẹwaa aarọ leyin igba ti wọn ṣe ayẹwo orukọ wọn ni ẹka idibo kẹrinla, Erungege, Ikenne wọọdu kinni, Ijọba ibilẹ Ikenne, ipinlẹ Ogun.

Nigba ti o n ba àwọn oniroyin sọrọ, Igbakeji Aarẹ Osinbajo ṣe apejuwe ètò naa gẹgẹ bi èyí tó dara julọ o si ni pe oun nigbagbọ pe bakan naa lori ni gbogbo orilẹ-ede Naijiria

O ni; “Mo ro pe bi ti ibudo mi ṣe ri, ti alaafia jọba, ti ko si rogbodiyan tabi ikunsinu nani ti ibudo miiran ri ooo’.

 

 

 

George Ọláyinká Akíntọ́lá.

 

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.