Take a fresh look at your lifestyle.
Election

Ìdìbò 2023: “Ẹgbẹ́ Òṣèlú APC Yóò Tẹ̀síwájú Láti máa Ṣe Dáadáa”-Ààrẹ Buhari

0 74

Ààrẹ Muhammadu Buhari ti ṣe afihan rẹ̀ pé àbájáde ìdìbò Gómìnà àti Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ìpínlẹ̀ yóò dáa fún ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress, APC, jákèjádò orílẹ̀-èdè náà.

O ni àwọn ọmọ Naijiria mọ ẹgbẹ naa si “ohun ti o sọ, ni yoo ṣe “

O sọrọ naa lọjọ Abamẹta Satide to kọja yii ni Daura, nipinlẹ Katsina lakoko to n ba àwọn oníròyìn sọrọ lẹyin ìbò rẹ̀.

Ààrẹ náà woye pe ko ya oun lẹnu ninu esi ibo Ààrẹ lọ́jọ́ kẹẹdogun osu keji ọdun 2023, eleyii ti Bola Tinubu jawe olubori gẹgẹ bi Aarẹ ti won dibo yan, niwon igba ti wọn ṣe iṣe wọn bíi iṣé.

 

 

George Ọláyinká Akíntọ́lá.

Leave A Reply

Your email address will not be published.