Take a fresh look at your lifestyle.
Election

Ibi tí Àjọ INEC yóò ti ṣe àkójọ èsì ìdìbò Gómìná ọdún 2023 Ti Ìpínlẹ̀ Jigawa.

0 65

Ibí yìí ni wọn yóò ti máa kó àwọn èsì ìbò ti Gómìnà ìpínlẹ̀ àti èsì ìbò ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ jọ.


Ibí yìí bákan náà ni wọn yóò ti máa kéde ẹni tó bá jáwé olúborí nínú ètò ìdìbò Gómìnà ati ilé Ìgbìmọ̀ aṣòfin ti ìpínlẹ̀ Jigawa

Leave A Reply

Your email address will not be published.