Olórí Àwọn Obinrin ọjà Rimi, ní Ipinlẹ Kano ní pé, ètò ìdìbò ń lọ ni ìrọwọ́-rọsẹ̀, ó ní àwọn ènìyàn tu jade lati wa dibo Gomina àti Ile Igbimọ Aṣofin Ọdun 2023, ti o si tun da loju pe, wọn a pọ ju bayii lọ nitori, ibo didi o ti kásẹ̀ nílẹ̀
Olórí Àwọn Obinrin ọjà Rimi, Hajia Hidayat Badhir lo sọ̀rọ̀ yìí lásìkò ètò ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò ti akọ̀ròyìn ilé Akéde Nàíjíríà, Voice of Nigeria, Hajia Rafat Salami sé pẹ̀lú Olórí Àwọn Ọlọja ni ipinlẹ Kano