Ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Estako ẹkùn ìwọ̀ oòrùn, wọọdu karun-un, ẹka kẹrin ni Ẹkùn Gúsù Ibie ile-iwe alaboyun, ti pari kika awọn iwe idibo, lakoko ti o wa ni ẹka kẹjọ àti mẹrinlelọgbọn ni wọọdu karun-un, idibo ṣi nlọ lọwọ pẹlu oludibo tí ò lóònkà.
Bakan naa, ni ẹka idibo karun-un, wọọdu kọkọnla, ile-iwe alakọbẹrẹ azama, ti bẹrẹ kika awọn iwe idibo náà
George Ọláyinká Akíntọ́lá.