Àbájáde èsì ìbò gómìná àti ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ní àwọn agbègbè kọ̀ọ̀kan ní ìpínlẹ̀ Jigawa ti bẹ̀rè
Àbájáde èsì ìbò gomina àti ile igbimọ asofin ipinle ni alwon wọ́ọ̀dù kọọkan ni ipinlẹ Jigawa ti bẹrẹ ni pẹrẹu
Èsì ìbò ilé-ìwé alakọbẹrẹ Gudan Sarkin Aska keji, ijọba ibilẹ Dutse, Ipinlẹ Jigawa ti jade
Èsì ìbò ile igbimọ asofin ipinlẹ ti ilé-ìwé alakọbẹrẹ kasarau ẹka idibo kẹfa, ijọba ibilẹ Dutse, olu-ilu Ipinlẹ Jigawa
APC:84
PDP:134
Èsì ìbò Gómìná
APC:77
PDP:138