Take a fresh look at your lifestyle.
Election

Iná Mọ́nà-mọ́na: Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ Buwọ́lù €3.7 Mílíọ̀nù

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 105

Àwọn ìgbìmọ̀ aláṣẹ tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní Ọjọ́rú fọwọ́sí ìyé owó tí ó tó mílíọ̀nù mẹ́ta-lé-méjé Euro €3.7 bi iyé owó àdéhùn fún Ilé-iṣẹ́ tó ń pèsè ìnà mọnamọna (Transition company of Nigeria) látí rá àwọn òun èlò látí túbọ parí iṣẹ́ àkànṣe tí àwọn ilé-iṣẹ́ mọnamọna méjì kàn tí yóò ṣé ìrànlọ́wọ́ fún igbelaruge ìpèsè iná ní orílẹ̀-èdè yìí.

Mínísítà fún ètò Iná, Abubakar Aliyu ló sọ èyí lásìkò tó ń bá àwọn oníròyìn Ilé-ìgbìmọ̀ aláṣẹ létí ní ìparí ìpàdé náà tí Ààrẹ Muhammadu Buhari dárí rẹ̀.

Mínísítà náà ṣàlàyé pé àdéhùn iṣẹ́ náà tí bẹ̀rẹ̀ ní ọdún 2006 ṣùgbọ́n wọ́n kọ́ọ̀sílẹ̀ nítorí áìní àgbàrá ìpèsè ìṣúná fún kíkọ́ àwọn ilé-iṣẹ́ mọnamọna òní 132 33KV ní Nnewi àtí 132KV ní Onitsha, méjèèjì ní Ìpínlẹ̀ Anambra.

Leave A Reply

Your email address will not be published.