Take a fresh look at your lifestyle.

Ìṣòro Wà Látí Ṣé Àwárí Duroonu Tó Já Sí Òkun Dúdú – Ìjọba America

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 138

Ọkọ ìjà òfurufú America kàn tí wọ́n fí ń wó àyíká Orílẹ̀-èdè Ukraine já lulẹ̀ lẹyìn tí ọkọ ìjà Òfurufú Russia ṣé ìkọlù sí. Èyí ló ṣòro látí wá lẹyìn tó jábo sínú ọ̀gbùn Okùn Dúdú, ọkàn nínú àwọn ọgá àgbà ọmọ ogún Orílẹ̀-èdè America sọ́, gẹ́gẹ́ bí ìjàbọ̀ tó jáde pé àwọn ọmọ ogún oju-omi Russia wà ní ààyè ìjàmbá náà.

Alága Ìgbìmọ̀ àwọn ọmọ ogún àpapọ America Gen. Mark Milley sọ pé, “ìyókù Duroonu MQ-9 náà tí ọkọ Òfurufú Orílẹ̀-èdè Russia Su-27 já sínú ọ̀gbùn Okùn Dúdú tí ó tó 1,219 sí 1,524 mítà èyí tó jẹ́ ìwọn ẹ̀sẹ̀ 4,000 sí 5,000.

Russia nínú ọrọ tirẹ̀ ‘kọ̀’ pé àwọn ọkọ òfurufú rẹ̀ kó lọ́wọ́ nínú iṣẹ̀lẹ̀ náà, ṣùgbọ́n òún yóò gbìyànjú láti wà àwọn ralẹ-ralẹ duroonu náà gẹ́gẹ́ bí ìròyìn ṣé sọ.

Tún kà nípa: Àwọn Ọmọ Ògún Russia Mú Misaili Ukraine Mẹ́tà Bálẹ̀ Ní Belgorod

Milley sọ pé America tí gbé àwọn ìgbésẹ látí ríi dájú pé kó sí àwọn òun èlò kọ̀ọ̀kan tó bá jẹ́ pé Russia yóò rí duroonu náà.

Òkun Dúdú ní ibodè Orílẹ̀-èdè Russia àtí Ukraine.

Leave A Reply

Your email address will not be published.