Take a fresh look at your lifestyle.
Election

Orílẹ̀-èdè Malawi: Ìjì Líle Freedy Pa Ènìyàn Mọ́kànlà.

0 94

Ọlópàá orílẹ̀-èdè Malawi sọ pé ènìyàn Mọ́kànlà lo ti jade láyé ti àwọn mẹ́rìndìnlógún sì di awati ni agbegbe Malawi ìlú ìkejì tó tóbi jùlọ ní Blantyre, lẹ̀yìn ìgbà tí òjò nlá fa àgbàrá àti ilé mímì ni ọjọ́ ajé.

 

Freedy jẹ ọkàn lára ìjì líle tó ti waye lọ́jọ́ tó tipé , ni gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ, ọdún 1994 ni iru re ti ṣẹlẹ̀ gbẹyin gbẹ̀yìn.

Agbẹnusọ fún àwọn ọlọ́pàá sọ wí pé Látàrí ìjàmbá náà àwọn ènìyàn tí yóò jáde láyé yóó pọ sí nítorí o tí sa koba fún agbegbe mẹwa báyìí.

 

Àwọn onímọ̀ sayẹnsi ni ìjàmbá yìí wáyé látàrí àwọn odò to n gbóná kọja bó ṣe yẹ.

Leave A Reply

Your email address will not be published.