Take a fresh look at your lifestyle.

Ọ̀gágun Àwọn Ológun Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Rọ Àwọn Ọmọ Ológun Láti Riwọ́ Àwọn Agbésùmọ̀mí Bọlẹ̀.

0 85

Ọ̀gágun àgbà àti aláṣẹ fún ẹkùn keje fún HADIN KAI ọgagun Waidi Shuiabu ti rọ àwọn ọmọ ogun Force Brigade lati gbaradì ni gbogbo igba ki wọn le koju awọn oniṣẹ láabi Boko Haram ati alatako ẹ̀sìn Musulumi.

Ọ̀gágun Shuiabu sọ èyí ni ọjọ́ àìkú ọjọ́ Kejìlá oṣù kẹta ọdún 2023, nigba ti o ṣe àbẹwò sí àwọn ọmọ ogun tí wọn ṣe ṣẹ gbe lo sí Gowza ni ìpìnlẹ̀ Borno.

O wà rọ àwọn ọmọ ogun na láti ní ìgboyà, ẹ̀kọ́, àti ìdánilójú lẹnu iṣẹ́ kí èyí lè mú wọn borí ìwà ìbàjẹ́.

 

O ní kí wọn yẹra fún ìwà ìbàjẹ́ àti ìwà tí kò tọ́

Leave A Reply

Your email address will not be published.