Take a fresh look at your lifestyle.

Aláàkóso Àjọ NYSC ṣe ìkìlọ̀ fún àwọn ará ìlú láti jáwọ́ wíwọ aṣọ àgùnbánirò lọ́nà àìtọ́

0 91

Alákoso fun àjọ ẹgbẹ́ àgùnbánirọ̀ lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ṣe ìkìlọ pàtàkì lórí ẹwu to wa ninu wiwọ aṣọ, lilo ààmì, orin àti àwọn èlò àgùnbánirọ̀ Lai gbà àṣẹ.

 

Ọ̀rọ̀ yìí jáde láti ọwó Olùdarí àti alukoro fún àjọ àgùnbánirọ̀, Ọ̀gbẹni Eddy Megwa, sọ wí pé àwọn ìròyìn ati ọ̀rọ̀ tí àwọn n gbọ nípa lílo aṣọ àgùnbánirọ̀ ko bojumu to.

 

O ní láti àkókò yíì lo àjọ àgùnbánirọ̀ yóò bẹ̀rẹ̀ sí ní mu eni to ba tápà sí òfin náà

Leave A Reply

Your email address will not be published.