Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Dárò ikú Sẹ́nítọ̀ Obìnrin Àkọ́kọ́.

0 136

Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Muhammad Buhari ti ba ẹbí àti ara kẹ́dùn ikú Sẹ́nítọ̀ Obìnrin àkọ́kọ́ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà France Afegbua èyí tí iṣé rẹ jẹ ìwúrí fún àwọn obìnrin.

Lábẹ àsìá ẹgbẹ́ òṣèlú National Party Of Nigerian (NPN). Ààrẹ ní itan ko ti pe Láì sí àwọn obìnrin,o ni ipa olóògbé nínú òṣèlú kò ṣe fowọ̀ rọ́ seyin .

Ààrẹ ni ikú rè jẹ ọ̀fọ̀ ńlá fún ìjọba àti àwọn ènìyàn ìpínlẹ̀ Edo, nibi ti o ti n gbé àwọn ènìyàn jáde nínú erọ̀fọ̀,tó sì ń se ìrànlọ́wọ́ fún ọpọlọpọ àwọn ènìyàn lọ́wọ́.

Ààrẹ gbàdúrà pé kí Olúwa tẹ olòógbè sáfẹ́fẹ́ réré, ó sí rọ àwọn ẹbí lati tèsíwájú nínú iṣẹ rere ti olóògbé fi sílẹ̀

Leave A Reply

Your email address will not be published.