Méjì nínú àwọn mẹ́rin ti àwọn oníṣe láabi Jígbé ni oju ibọn ni orílẹ̀-èdè Mexico lo ti jade laye nígbà tí àwọn méjì tókù sí ti padà sí orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.
Àwọn mẹ́rin ní àwọn ajinigbe kò ní ọjọ́ kẹta oṣù kẹta ọdún 2023 nígbà tí wọn n ri ìrin àjọ lọ sí ìlú Matamoros ni orílẹ́-èdè Mexico .
Wọn ní Matamoros je ìlú tó léwu julọ ni orílẹ̀-èdè náà nítorí ìwà ìbàjẹ́ pọ̀jù nibe .