Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Buhari Ki Igbákejì Re Yẹmi Osinbajo Ku Oríre Ọjọ́ Ìbí Rẹ.

0 47

Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Muhammed Buhari ba ìgbákejì rẹ ọ̀mọ̀wé Osinbajo àti ẹbí rè ṣe àjoyọ̀ ayẹyẹ ọjọ-ibi re ní ẹni ọdún mẹ́rìndínlọ́gọ́ta ni òní .

 

Ọlọjọ ìbí ni ohun dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọrun to mu ohun rí ọdún míràn láti ṣiṣẹ ìlú àti ìjọ.

Leave A Reply

Your email address will not be published.