Take a fresh look at your lifestyle.

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Rivers Ṣé Ìfilọ́lẹ̀ Pápákọ̀ Òfurufú Ní Olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

1 101

Gómìnà Nyesom Wike ti ìpínlẹ̀ Rivers tí ṣé ìfilọ́lẹ̀ ìṣẹ́ àkànṣe mẹ́ta bíí, ilé èpò ọkọ̀ òfurufú, ọ̀nà àbáwọlé pápá ọkọ̀ òfurufú àti ọgbà ìtura, gbogbo rẹ̀ ní pápákọ̀ òfurufú Ìbàdàn, olú ìlú ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.

Wike ṣé ìfilọ́lẹ̀ ilé ọkọ̀ òfurufú òní ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọ̀ọ́dẹ́gbẹ̀ta lita (500,000 liters), òpópó-ònà Dr Victor Omololu Olunloyo ònígbá méjì tó jẹ́ kilomita mẹ́ta lé méjì 3.2km àtí kíkọ́ ilé ìgbàlódé Dr Victor Omololu Olunloyo Park.

Níbí ayẹyẹ náà, Gómìnà Wike tí gbóríyìn fún Gómìnà Makinde tí Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ fún ṣíṣétò ìṣẹ́ àkànṣe nlá náà “Èyí jẹ́ ìtàn, nítorí pé ọjọ́ àkọ́kọ́ tí ọkọ̀ òfurufú yóò gbà èpò tí yóò sì tèsíwájú nínú ìrìn àjò rẹ̀. Tí Ó bá lé ṣé èyí ní sáà àkọ́kọ́ rẹ̀, kí lá ró pé yóò ṣé ní sáà Kejì rẹ̀? Ẹ́ jẹ́ kí á dìbo wà fún.”

Wike sọ pé: “Lónì, àtí fí ìtàn bálẹ̀ pé gbogbo wà mọ pé nígbà tí Ààrẹ bá parí látí Gúsù, yóò lọ sí Àríwá; nígbà tí o bá parí látí Àríwá, yóò lọ sí Gúsù. Kó nílò kí a kọ̀ sínú ìwé òfin kánkan kí o tó dì imusẹ, mó sì dúpẹ lọ́wọ́ àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà fún bí wọ́n tí dúró ṣinṣin látí ríi pé ọrọ náà wá sí imuṣẹ.”

Tún kà nípa: Ìdìbò Ọdún 2023 – Makinde Ṣèlérí Láti Sọ Odò Adágún Ado-awaye Dì Ibùdó Ìgbafẹ́

Nínú ọrọ rẹ̀ níbí ayẹyẹ náà, Gómìnà Seyi Makinde tó jẹ́ olugbalejo, ẹní tó fi ìdùnnú rẹ̀ hàn pé àlà òún látí rí pé bàálù gbéra tàbí bálẹ̀ sí pápákọ̀ òfurufú Ibadan tí dì ìmúṣẹ́. Ó ní òún tún ní ìgbàgbọ́ wípé ní ọjọ́ kàn yóò di pápákọ̀ òfurufú tí yóò máa gbàlèjò bàálù lágbayé.

Leave A Reply

Your email address will not be published.