Ẹgbẹ́ òṣèlú People’s Democratic Party,PDP gùnlé ètò ìwọ́de lọ sí ilé -isẹ́ àjọ elétò ìdìbò lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà
Ẹgbẹ́ òṣèlú People’s Democratic Party,PDP gùnlé ètò ìwọ́de lọ sí ilé -isẹ́ àjọ elétò ìdìbò lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà láti fí ẹ̀hónú hàn látàrí èsì ìbò ààrẹ ti àjọ INEC kéde . pé Asiwaju Bola Ahmed Tinubu ló jáwé olúborí nínú ètò ìdìbò náà.
Ẹgbẹ́ òṣèlú PDP kọ ìwé ẹ̀hónú ìyẹn Petition láti tako àbájáde èsì ìbò ààrẹ ọ̀hún
Ọláyinká Akíntọ́lá.
Leave a Reply