Ààrẹ Vladimir Putin yóò ṣàlàyé fún àwọn ìgbìmọ̀ orílẹ̀-èdè Russian lori ija to nlọ lọwọ ni orílẹ̀-èdè Ukraine ni ọjọ́ ìṣẹgun.
Ààrẹ Putin yóò sọ àwọn ohun tí ó lò láti jagun náà pèlú orílẹ̀-èdè Ukraine àti àwọn ètò pàtàkì tí ò lò láti rí wí pé ìdàgbàsókè bá àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè rẹ lakoko ogun náà.
Ó ni àwọn ènìyàn tó tó ẹgbẹ̀rún ni wón ti jáde láyé látàrí ìjà naa, ó sọ́ di mímọ̀ wí pé orílẹ̀-èdè Russian ti wà nínú agbami ija nlá báyìí nípa èyí tí wọ́n fẹ́ fi jí wa àwọn ohun ìní àti àlùmọ́nì.
[…] […]