Take a fresh look at your lifestyle.

Àpapọ̀ Ẹgbẹ́ Àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ Bú Ọlá Fún Ọ̀gá Àgbà pátápátá fún Àjọ PenCom.

0 175

Ẹgbẹ́ àwọn akékọ̀ọ́ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà NANS tí bu ọlá fún adarí pátápátá fún àjọ to ń mójú tó àwọn tọ ti feyinti lẹnu iṣẹ́, ìyáàfin Aisha Dahir- Umar gẹ́gẹ́ bí ènìyàn ma lé gbàgbé Lágbàáyé látàrí iṣẹ́ takuntakun rẹ lẹnu iṣẹ́.

Ẹgbẹ́ àwọn akékọ̀ọ́ ṣe àpọ̀nlé fún ìyáàfin Dahir-Umar nípa fífún ni àmì ẹ̀yẹ fún àtìlẹ́yìn àti ìdàgbàsókè rẹ fún àwọn ọ̀dọ́ àti akẹ́kọ̀ọ́

Ààrẹ fún ẹgbẹ́ àwọn akékọ̀ọ́ kọ́múrèdì Attah Felix Nnalue sọ wí pé àmì ẹ̀yẹ náà wà fún àwọn ènìyàn tó ṣiṣẹ takuntakun fún ìlọsíwájú àti ìdàgbàsókè orílẹ̀-èdè àti àwọn ènìyàn.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button