Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn Ọmọ Orílẹ̀ Èdè Egypt Fi Ohun Ìtura Ráńsẹ́ Sí Syria

0 216

Àwọn ọmọ Orílẹ̀ Èdè Egypt ti fi àwọn ohun ìrànwọ́ àti ìtunilára ráńsẹ́ sí àwọn tí ó fi ara káásá níbi ìsẹ̀lẹ̀ ilẹ̀ rírì ní Orílẹ̀ Èdè Syria.

 

Lára àwọn ohun èlò náà ni Aṣọ, Oúnjẹ àti mílíìkì tí ó jẹ́ oúnjẹ àwọn ọmọdé.

 

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọmọ Orílẹ̀ Èdè Egypt ni ó dìde ìrànlọ́wọ́ náà tí wọn sì gbarata, nítorí pé ó tó ẹgbẹ̀rú mẹ́tàlélógún ènìyàn tí ó bá ìjàm̀bá ilẹ̀ rírì náà lọ, tí ó sì dá wàhálà ńlá sílẹ̀ ní Orílẹ̀ Èdè náà.

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button