Take a fresh look at your lifestyle.

Adarí Orílẹ̀-èdè Toronto Kọ̀wẹ́ Fi ṣẹ́ Sílẹ̀ 

0 235

Adarí Orílẹ̀-èdè Toronto  John Tory kọ̀wé fi ṣé sílẹ̀, lẹ́yìn ìgbà tí akọ ìròyìn kàn fi ẹsùn kàn wí pé ó ní nkán pọ̀ pẹ̀lú ọmọ iṣé rẹ tó kéré sí púpọ̀.

Ni ọjọ́ ẹtì ní Tory tó jẹ ẹni ọdún méjìdínláàdọ́rin sọ wí pé ìbáṣepọ̀ náà ti dọ́pin ni ìbẹ̀rẹ̀ ọdún yìí àti wí pé ọmọ iṣé ohun náà ti kúrò ní akátá òhun.

Mo tọrọ aforiji fún ìwà ìbàjẹ́ ti mo hun sí àwọn ènìyàn Toronto ati gbogbo àwọn tí ọ̀rọ̀ náà ṣe àkóbá fún.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button